Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 46 - صٓ - Page - Juz 23
﴿إِنَّآ أَخۡلَصۡنَٰهُم بِخَالِصَةٖ ذِكۡرَى ٱلدَّارِ ﴾
[صٓ: 46]
﴿إنا أخلصناهم بخالصة ذكرى الدار﴾ [صٓ: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa ṣà wọ́n lẹ́ṣà pẹ̀lú ẹ̀ṣà kan; ìrántí Ilé Ìkẹ́yìn |