Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 47 - صٓ - Page - Juz 23
﴿وَإِنَّهُمۡ عِندَنَا لَمِنَ ٱلۡمُصۡطَفَيۡنَ ٱلۡأَخۡيَارِ ﴾
[صٓ: 47]
﴿وإنهم عندنا لمن المصطفين الأخيار﴾ [صٓ: 47]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú wọ́n wà nínú àwọn ẹni ẹ̀ṣà, ẹni rere jùlọ ní ọ̀dọ̀ Wa |