Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 11 - الزُّمَر - Page - Juz 23
﴿قُلۡ إِنِّيٓ أُمِرۡتُ أَنۡ أَعۡبُدَ ٱللَّهَ مُخۡلِصٗا لَّهُ ٱلدِّينَ ﴾
[الزُّمَر: 11]
﴿قل إني أمرت أن أعبد الله مخلصا له الدين﴾ [الزُّمَر: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Dájúdájú Wọ́n pa mí ní àṣẹ pé kí n̄g jọ́sìn fún Allāhu ní ti olùṣe-àfọ̀mọ́-ẹ̀sìn fún Un |