Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 40 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿مَن يَأۡتِيهِ عَذَابٞ يُخۡزِيهِ وَيَحِلُّ عَلَيۡهِ عَذَابٞ مُّقِيمٌ ﴾
[الزُّمَر: 40]
﴿من يأتيه عذاب يخزيه ويحل عليه عذاب مقيم﴾ [الزُّمَر: 40]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni ẹni tí ìyà tí ó máa yẹpẹrẹ rẹ̀ máa dé bá, tí ìyà gbere sì máa kò lé lórí |