Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 60 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿وَيَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ تَرَى ٱلَّذِينَ كَذَبُواْ عَلَى ٱللَّهِ وُجُوهُهُم مُّسۡوَدَّةٌۚ أَلَيۡسَ فِي جَهَنَّمَ مَثۡوٗى لِّلۡمُتَكَبِّرِينَ ﴾
[الزُّمَر: 60]
﴿ويوم القيامة ترى الذين كذبوا على الله وجوههم مسودة أليس في جهنم﴾ [الزُّمَر: 60]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé ní Ọjọ́ Àjíǹde, o máa rí àwọn t’ó parọ́ mọ́ Allāhu tí ojú wọn máa dúdú. Ṣé inú iná Jahnamọ kọ́ ni ibùgbé fún àwọn onígbèéraga ni |