×

Dajudaju Awa so Tira (al-Ƙur’an) kale fun o pelu ododo nitori ki 4:105 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:105) ayat 105 in Yoruba

4:105 Surah An-Nisa’ ayat 105 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 105 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿إِنَّآ أَنزَلۡنَآ إِلَيۡكَ ٱلۡكِتَٰبَ بِٱلۡحَقِّ لِتَحۡكُمَ بَيۡنَ ٱلنَّاسِ بِمَآ أَرَىٰكَ ٱللَّهُۚ وَلَا تَكُن لِّلۡخَآئِنِينَ خَصِيمٗا ﴾
[النِّسَاء: 105]

Dajudaju Awa so Tira (al-Ƙur’an) kale fun o pelu ododo nitori ki o le baa sedajo laaarin awon eniyan pelu ohun ti Allahu fi han o. Ma se je olugbeja fun awon onijanba

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إنا أنـزلنا إليك الكتاب بالحق لتحكم بين الناس بما أراك الله ولا, باللغة اليوربا

﴿إنا أنـزلنا إليك الكتاب بالحق لتحكم بين الناس بما أراك الله ولا﴾ [النِّسَاء: 105]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú Àwa sọ Tírà (al-Ƙur’ān) kalẹ̀ fún ọ pẹ̀lú òdodo nítorí kí o lè baà ṣèdájọ́ láààrin àwọn ènìyàn pẹ̀lú ohun tí Allāhu fi hàn ọ́. Má ṣe jẹ́ olùgbèjà fún àwọn oníjàǹbá
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek