Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 118 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿لَّعَنَهُ ٱللَّهُۘ وَقَالَ لَأَتَّخِذَنَّ مِنۡ عِبَادِكَ نَصِيبٗا مَّفۡرُوضٗا ﴾
[النِّسَاء: 118]
﴿لعنه الله وقال لأتخذن من عبادك نصيبا مفروضا﴾ [النِّسَاء: 118]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu ṣẹ́bi lé Èṣù. Ó sì wí pé: "Dájúdájú mo máa mú ìpín tí wọ́n pín fún mi nínú àwọn ẹrúsìn Rẹ |