×

E o le se deede (ninu ife) laaarin awon obinrin, e o 4:129 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:129) ayat 129 in Yoruba

4:129 Surah An-Nisa’ ayat 129 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 129 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿وَلَن تَسۡتَطِيعُوٓاْ أَن تَعۡدِلُواْ بَيۡنَ ٱلنِّسَآءِ وَلَوۡ حَرَصۡتُمۡۖ فَلَا تَمِيلُواْ كُلَّ ٱلۡمَيۡلِ فَتَذَرُوهَا كَٱلۡمُعَلَّقَةِۚ وَإِن تُصۡلِحُواْ وَتَتَّقُواْ فَإِنَّ ٱللَّهَ كَانَ غَفُورٗا رَّحِيمٗا ﴾
[النِّسَاء: 129]

E o le se deede (ninu ife) laaarin awon obinrin, e o baa jerankan re. Nitori naa, e ma se fi sibi kan tan raurau, ki e ma lo pa (eni kan) ti bi ohun agbeko. Ti e ba satunse, ti e si beru (Allahu), dajudaju Allahu n je Alaforijin, Asake-orun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولن تستطيعوا أن تعدلوا بين النساء ولو حرصتم فلا تميلوا كل الميل, باللغة اليوربا

﴿ولن تستطيعوا أن تعدلوا بين النساء ولو حرصتم فلا تميلوا كل الميل﴾ [النِّسَاء: 129]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ẹ ò lè ṣe déédé (nínú ìfẹ́) láààrin àwọn obìnrin, ẹ ò báà jẹ̀rankàn rẹ̀. Nítorí náà, ẹ má ṣe fì síbì kan tán ráúráú, kí ẹ má lọ pa (ẹnì kan) tì bí ohun àgbékọ́. Tí ẹ bá ṣàtúnṣe, tí ẹ sì bẹ̀rù (Allāhu), dájúdájú Allāhu ń jẹ́ Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek