×

Eyin eniyan, dajudaju Ojise naa ti de ba yin pelu ododo lati 4:170 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:170) ayat 170 in Yoruba

4:170 Surah An-Nisa’ ayat 170 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 170 - النِّسَاء - Page - Juz 6

﴿يَٰٓأَيُّهَا ٱلنَّاسُ قَدۡ جَآءَكُمُ ٱلرَّسُولُ بِٱلۡحَقِّ مِن رَّبِّكُمۡ فَـَٔامِنُواْ خَيۡرٗا لَّكُمۡۚ وَإِن تَكۡفُرُواْ فَإِنَّ لِلَّهِ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۚ وَكَانَ ٱللَّهُ عَلِيمًا حَكِيمٗا ﴾
[النِّسَاء: 170]

Eyin eniyan, dajudaju Ojise naa ti de ba yin pelu ododo lati odo Oluwa yin. Nitori naa, ki e gba a gbo l’o dara julo fun yin. Ti e ba si sai gbagbo, dajudaju ti Allahu ni ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ile. Allahu si n je Onimo, Ologbon

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ياأيها الناس قد جاءكم الرسول بالحق من ربكم فآمنوا خيرا لكم وإن, باللغة اليوربا

﴿ياأيها الناس قد جاءكم الرسول بالحق من ربكم فآمنوا خيرا لكم وإن﴾ [النِّسَاء: 170]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ẹ̀yin ènìyàn, dájúdájú Òjíṣẹ́ náà ti dé ba yín pẹ̀lú òdodo láti ọ̀dọ̀ Olúwa yín. Nítorí náà, kí ẹ gbà á gbọ́ l’ó dára jùlọ fun yín. Tí ẹ bá sì ṣàì gbàgbọ́, dájúdájú ti Allāhu ni ohunkóhun t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Allāhu sì ń jẹ́ Onímọ̀, Ọlọ́gbọ́n
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek