Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 27 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿وَٱللَّهُ يُرِيدُ أَن يَتُوبَ عَلَيۡكُمۡ وَيُرِيدُ ٱلَّذِينَ يَتَّبِعُونَ ٱلشَّهَوَٰتِ أَن تَمِيلُواْ مَيۡلًا عَظِيمٗا ﴾
[النِّسَاء: 27]
﴿والله يريد أن يتوب عليكم ويريد الذين يتبعون الشهوات أن تميلوا ميلا﴾ [النِّسَاء: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé Allāhu fẹ́ gba ìronúpìwàdà yín. Àwọn t’ó sì ń tẹ̀lé ìfẹ́-adùn ayé sì ń fẹ́ kí ẹ yẹ̀ kúrò (nínú ẹ̀sìn) ní yíyẹ̀ t’ó tóbi |