×

Dajudaju o n be ninu yin eni t’o n fa seyin. Ti 4:72 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:72) ayat 72 in Yoruba

4:72 Surah An-Nisa’ ayat 72 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 72 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿وَإِنَّ مِنكُمۡ لَمَن لَّيُبَطِّئَنَّ فَإِنۡ أَصَٰبَتۡكُم مُّصِيبَةٞ قَالَ قَدۡ أَنۡعَمَ ٱللَّهُ عَلَيَّ إِذۡ لَمۡ أَكُن مَّعَهُمۡ شَهِيدٗا ﴾
[النِّسَاء: 72]

Dajudaju o n be ninu yin eni t’o n fa seyin. Ti adanwo kan ba kan yin, o maa wi pe: "Allahu kuku ti se idera fun mi nitori pe emi ko si nibe pelu won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وإن منكم لمن ليبطئن فإن أصابتكم مصيبة قال قد أنعم الله علي, باللغة اليوربا

﴿وإن منكم لمن ليبطئن فإن أصابتكم مصيبة قال قد أنعم الله علي﴾ [النِّسَاء: 72]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú ó ń bẹ nínú yín ẹni t’ó ń fà sẹ́yìn. Tí àdánwó kan bá kàn yín, ó máa wí pé: "Allāhu kúkú ti ṣe ìdẹ̀ra fún mi nítorí pé èmi kò sí níbẹ̀ pẹ̀lú wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek