Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 80 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿مَّن يُطِعِ ٱلرَّسُولَ فَقَدۡ أَطَاعَ ٱللَّهَۖ وَمَن تَوَلَّىٰ فَمَآ أَرۡسَلۡنَٰكَ عَلَيۡهِمۡ حَفِيظٗا ﴾
[النِّسَاء: 80]
﴿من يطع الرسول فقد أطاع الله ومن تولى فما أرسلناك عليهم حفيظا﴾ [النِّسَاء: 80]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni t’ó bá tẹ̀lé Òjíṣẹ́ náà, ó ti tẹ̀lé (àṣẹ) Allāhu. Ẹnikẹ́ni t’ó bá sì pẹ̀yìndà, A ò rán ọ níṣẹ́ olùṣọ́ lórí wọn |