×

Won n wi pe: “A tele ase re.” Sugbon nigba ti won 4:81 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:81) ayat 81 in Yoruba

4:81 Surah An-Nisa’ ayat 81 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 81 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿وَيَقُولُونَ طَاعَةٞ فَإِذَا بَرَزُواْ مِنۡ عِندِكَ بَيَّتَ طَآئِفَةٞ مِّنۡهُمۡ غَيۡرَ ٱلَّذِي تَقُولُۖ وَٱللَّهُ يَكۡتُبُ مَا يُبَيِّتُونَۖ فَأَعۡرِضۡ عَنۡهُمۡ وَتَوَكَّلۡ عَلَى ٱللَّهِۚ وَكَفَىٰ بِٱللَّهِ وَكِيلًا ﴾
[النِّسَاء: 81]

Won n wi pe: “A tele ase re.” Sugbon nigba ti won ba jade kuro lodo re, igun kan ninu won maa gbimo nnkan ti o yato si eyi ti n so (losan-an). Allahu si n se akosile ohun ti won n gbimo loru. Nitori naa, seri kuro lodo won, ki o si gbarale Allahu. Allahu si to Alaabo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ويقولون طاعة فإذا برزوا من عندك بيت طائفة منهم غير الذي تقول, باللغة اليوربا

﴿ويقولون طاعة فإذا برزوا من عندك بيت طائفة منهم غير الذي تقول﴾ [النِّسَاء: 81]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Wọ́n ń wí pé: “A tẹ̀lé àṣẹ rẹ.” Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n bá jáde kúrò lọ́dọ̀ rẹ, igun kan nínú wọn máa gbìmọ̀ n̄ǹkan tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ń sọ (lọ́sàn-án). Allāhu sì ń ṣe àkọsílẹ̀ ohun tí wọ́n ń gbìmọ̀ lóru. Nítorí náà, ṣẹ́rí kúrò lọ́dọ̀ wọn, kí o sì gbáralé Allāhu. Allāhu sì tó Aláàbò
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek