×

Nitori naa, jagun fun esin Allahu. Won ko la a bo eni 4:84 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:84) ayat 84 in Yoruba

4:84 Surah An-Nisa’ ayat 84 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 84 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿فَقَٰتِلۡ فِي سَبِيلِ ٱللَّهِ لَا تُكَلَّفُ إِلَّا نَفۡسَكَۚ وَحَرِّضِ ٱلۡمُؤۡمِنِينَۖ عَسَى ٱللَّهُ أَن يَكُفَّ بَأۡسَ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْۚ وَٱللَّهُ أَشَدُّ بَأۡسٗا وَأَشَدُّ تَنكِيلٗا ﴾
[النِّسَاء: 84]

Nitori naa, jagun fun esin Allahu. Won ko la a bo eni kan lorun afi iwo. Ki o si gbe awon onigbagbo ododo longbe ogun esin jija. O see se ki Allahu ka owoja awon t’o sai gbagbo duro. Ati pe Allahu le julo (nibi) ija. O si le julo nibi ijeni-niya

❮ Previous Next ❯

ترجمة: فقاتل في سبيل الله لا تكلف إلا نفسك وحرض المؤمنين عسى الله, باللغة اليوربا

﴿فقاتل في سبيل الله لا تكلف إلا نفسك وحرض المؤمنين عسى الله﴾ [النِّسَاء: 84]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Nítorí náà, jagun fún ẹ̀sìn Allāhu. Wọn kò là á bọ ẹnì kan lọ́rùn àfi ìwọ. Kí o sì gbẹ àwọn onígbàgbọ́ òdodo lóǹgbẹ ogun ẹ̀sìn jíjà. Ó ṣeé ṣe kí Allāhu ká ọwọ́jà àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ dúró. Àti pé Allāhu le jùlọ (níbi) ìjà. Ó sì le jùlọ níbi ìjẹni-níyà
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek