Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 14 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿فَٱدۡعُواْ ٱللَّهَ مُخۡلِصِينَ لَهُ ٱلدِّينَ وَلَوۡ كَرِهَ ٱلۡكَٰفِرُونَ ﴾
[غَافِر: 14]
﴿فادعوا الله مخلصين له الدين ولو كره الكافرون﴾ [غَافِر: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹ pe Allāhu ní ti olùṣàfọ̀mọ́-ẹ̀sìn fún Un, àwọn aláìgbàgbọ́ ìbáà kórira Rẹ̀ |