Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 31 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿مِثۡلَ دَأۡبِ قَوۡمِ نُوحٖ وَعَادٖ وَثَمُودَ وَٱلَّذِينَ مِنۢ بَعۡدِهِمۡۚ وَمَا ٱللَّهُ يُرِيدُ ظُلۡمٗا لِّلۡعِبَادِ ﴾
[غَافِر: 31]
﴿مثل دأب قوم نوح وعاد وثمود والذين من بعدهم وما الله يريد﴾ [غَافِر: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Irú ìṣe (ìparun t’ó ṣẹlẹ̀ sí àwọn) ènìyàn Nūh, ‘Ād, Thamūd àti àwọn t’ó tẹ̀lé wọn. Allāhu kò sì gbèrò àbòsí sí àwọn ẹrúsìn náà |