Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 30 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿وَقَالَ ٱلَّذِيٓ ءَامَنَ يَٰقَوۡمِ إِنِّيٓ أَخَافُ عَلَيۡكُم مِّثۡلَ يَوۡمِ ٱلۡأَحۡزَابِ ﴾
[غَافِر: 30]
﴿وقال الذي آمن ياقوم إني أخاف عليكم مثل يوم الأحزاب﴾ [غَافِر: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni t’ó gbàgbọ́ ní òdodo tún sọ pé: "Ẹ̀yin ènìyàn mi, dájúdájú irú ọjọ́ (ẹ̀san ìyà t’ó ṣẹlẹ̀ sí) àwọn ọmọ-ogun oníjọ ni èmi ń páyà lórí yín |