Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 45 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿فَوَقَىٰهُ ٱللَّهُ سَيِّـَٔاتِ مَا مَكَرُواْۖ وَحَاقَ بِـَٔالِ فِرۡعَوۡنَ سُوٓءُ ٱلۡعَذَابِ ﴾
[غَافِر: 45]
﴿فوقاه الله سيئات ما مكروا وحاق بآل فرعون سوء العذاب﴾ [غَافِر: 45]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu sì ṣọ́ ọ níbi àwọn aburú tí wọ́n dète rẹ̀. Ìyà burúkú sì yí àwọn ènìyàn Fir‘aon po |