Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 6 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿وَكَذَٰلِكَ حَقَّتۡ كَلِمَتُ رَبِّكَ عَلَى ٱلَّذِينَ كَفَرُوٓاْ أَنَّهُمۡ أَصۡحَٰبُ ٱلنَّارِ ﴾
[غَافِر: 6]
﴿وكذلك حقت كلمة ربك على الذين كفروا أنهم أصحاب النار﴾ [غَافِر: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé báyẹn ni ọ̀rọ̀ Olúwa rẹ ṣe kò lórí àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ pé: "Dájúdájú àwọn ni èrò inú Iná |