Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 71 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿إِذِ ٱلۡأَغۡلَٰلُ فِيٓ أَعۡنَٰقِهِمۡ وَٱلسَّلَٰسِلُ يُسۡحَبُونَ ﴾
[غَافِر: 71]
﴿إذ الأغلال في أعناقهم والسلاسل يسحبون﴾ [غَافِر: 71]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí àwọn sẹ́kẹ́sẹkẹ̀ àti ẹ̀wọ̀n bá wà ní ọrùn wọn, tí wọn yóò fi máa wọ́ wọn |