Quran with Yoruba translation - Surah Fussilat ayat 8 - فُصِّلَت - Page - Juz 24
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ لَهُمۡ أَجۡرٌ غَيۡرُ مَمۡنُونٖ ﴾
[فُصِّلَت: 8]
﴿إن الذين آمنوا وعملوا الصالحات لهم أجر غير ممنون﴾ [فُصِّلَت: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe àwọn iṣẹ́ rere, ẹ̀san tí kò níí pẹ̀dín ń bẹ fún wọn |