Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 39 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿وَٱلَّذِينَ إِذَآ أَصَابَهُمُ ٱلۡبَغۡيُ هُمۡ يَنتَصِرُونَ ﴾
[الشُّوري: 39]
﴿والذين إذا أصابهم البغي هم ينتصرون﴾ [الشُّوري: 39]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ohun tí ó wà lọ́dọ̀ Allāhu tún wà fún) àwọn tí (ó jẹ́ pé) nígbà tí wọ́n bá ṣe àbòsí sí wọn, wọn yóò gbẹ̀san wọn padà |