Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 47 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿ٱسۡتَجِيبُواْ لِرَبِّكُم مِّن قَبۡلِ أَن يَأۡتِيَ يَوۡمٞ لَّا مَرَدَّ لَهُۥ مِنَ ٱللَّهِۚ مَا لَكُم مِّن مَّلۡجَإٖ يَوۡمَئِذٖ وَمَا لَكُم مِّن نَّكِيرٖ ﴾
[الشُّوري: 47]
﴿استجيبوا لربكم من قبل أن يأتي يوم لا مرد له من الله﴾ [الشُّوري: 47]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ jẹ́pè Olúwa yín ṣíwájú kí ọjọ́ kan tó de, tí kò sí ìdápadà kan fún un ní ọ̀dọ̀ Allāhu. Kò sí ibùsásí kan fun yín ní ọjọ́ yẹn. Kò sì níí sí olùkọ̀yà kan fun yín |