Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 45 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَسۡـَٔلۡ مَنۡ أَرۡسَلۡنَا مِن قَبۡلِكَ مِن رُّسُلِنَآ أَجَعَلۡنَا مِن دُونِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ءَالِهَةٗ يُعۡبَدُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 45]
﴿واسأل من أرسلنا من قبلك من رسلنا أجعلنا من دون الرحمن آلهة﴾ [الزُّخرُف: 45]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Bèèrè wò lọ́wọ́ àwọn tí A rán níṣẹ́ ṣíwájú rẹ nínú àwọn Òjíṣẹ́ Wa (pé): "Ǹjẹ́ A sọ àwọn kan di ọlọ́hun tí wọn yóò máa jọ́sìn fún lẹ́yìn Àjọkẹ́-ayé bí |