Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 44 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَإِنَّهُۥ لَذِكۡرٞ لَّكَ وَلِقَوۡمِكَۖ وَسَوۡفَ تُسۡـَٔلُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 44]
﴿وإنه لذكر لك ولقومك وسوف تسألون﴾ [الزُّخرُف: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú al-Ƙur’ān ni tírà ìrántí fún ìwọ àti ìjọ rẹ. Láìpẹ́ Wọ́n máa bi yín léèrè (nípa rẹ̀) |