Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 5 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿أَفَنَضۡرِبُ عَنكُمُ ٱلذِّكۡرَ صَفۡحًا أَن كُنتُمۡ قَوۡمٗا مُّسۡرِفِينَ ﴾
[الزُّخرُف: 5]
﴿أفنضرب عنكم الذكر صفحا أن كنتم قوما مسرفين﴾ [الزُّخرُف: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé kí Á ká Tírà Ìrántí (al-Ƙur’ān) kúrò nílẹ̀ fun yín, kí Á máa wò yín níran nítorí pé ẹ jẹ́ ìjọ alákọyọ |