Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 56 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿فَجَعَلۡنَٰهُمۡ سَلَفٗا وَمَثَلٗا لِّلۡأٓخِرِينَ ﴾
[الزُّخرُف: 56]
﴿فجعلناهم سلفا ومثلا للآخرين﴾ [الزُّخرُف: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì ṣe wọ́n ní ìjọ aṣíwájú (nínú ìparun) àti àpẹẹrẹ (fèyíkọ́gbọ́n) fún àwọn ẹni ìkẹ́yìn |