Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 57 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿۞ وَلَمَّا ضُرِبَ ٱبۡنُ مَرۡيَمَ مَثَلًا إِذَا قَوۡمُكَ مِنۡهُ يَصِدُّونَ ﴾
[الزُّخرُف: 57]
﴿ولما ضرب ابن مريم مثلا إذا قومك منه يصدون﴾ [الزُّخرُف: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí àwọn ọ̀ṣẹbọ fi ọmọ Mọryam ṣe àpẹẹrẹ (fún òrìṣà wọn), nígbà náà ni àwọn ènìyàn rẹ bá ń fi (àpẹẹrẹ náà) rẹ́rìn-ín |