Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 82 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿سُبۡحَٰنَ رَبِّ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ رَبِّ ٱلۡعَرۡشِ عَمَّا يَصِفُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 82]
﴿سبحان رب السموات والأرض رب العرش عما يصفون﴾ [الزُّخرُف: 82]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mímọ́ ni fún Olúwa àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀, Olúwa Ìtẹ́-ọlá tayọ irọ́ tí wọ́n ń pa (mọ́ Ọn) |