Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 81 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿قُلۡ إِن كَانَ لِلرَّحۡمَٰنِ وَلَدٞ فَأَنَا۠ أَوَّلُ ٱلۡعَٰبِدِينَ ﴾
[الزُّخرُف: 81]
﴿قل إن كان للرحمن ولد فأنا أول العابدين﴾ [الزُّخرُف: 81]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Kò sí ọmọ kan fún Àjọké ayé. Nítorí náà, èmi ni ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn olùjọ́sìn (fún Allāhu ní àsìkò tèmi) |