Quran with Yoruba translation - Surah Muhammad ayat 9 - مُحمد - Page - Juz 26
﴿ذَٰلِكَ بِأَنَّهُمۡ كَرِهُواْ مَآ أَنزَلَ ٱللَّهُ فَأَحۡبَطَ أَعۡمَٰلَهُمۡ ﴾
[مُحمد: 9]
﴿ذلك بأنهم كرهوا ما أنـزل الله فأحبط أعمالهم﴾ [مُحمد: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn nítorí pé dájúdájú wọ́n kórira ohun tí Allāhu sọ̀kalẹ̀. Nítorí náà, (Allāhu) sì ba iṣẹ́ wọn jẹ́ |