×

Rara (ki i se ise kan l’o di yin lowo lati lo 48:12 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Fath ⮕ (48:12) ayat 12 in Yoruba

48:12 Surah Al-Fath ayat 12 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fath ayat 12 - الفَتح - Page - Juz 26

﴿بَلۡ ظَنَنتُمۡ أَن لَّن يَنقَلِبَ ٱلرَّسُولُ وَٱلۡمُؤۡمِنُونَ إِلَىٰٓ أَهۡلِيهِمۡ أَبَدٗا وَزُيِّنَ ذَٰلِكَ فِي قُلُوبِكُمۡ وَظَنَنتُمۡ ظَنَّ ٱلسَّوۡءِ وَكُنتُمۡ قَوۡمَۢا بُورٗا ﴾
[الفَتح: 12]

Rara (ki i se ise kan l’o di yin lowo lati lo jagun, amo) e ti lero pe Ojise ati awon onigbagbo ododo ko nii pada si odo ara ile won mo laelae. Won se iyen ni oso sinu okan yin. E si ro ero aburu. E si je ijo iparun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: بل ظننتم أن لن ينقلب الرسول والمؤمنون إلى أهليهم أبدا وزين ذلك, باللغة اليوربا

﴿بل ظننتم أن لن ينقلب الرسول والمؤمنون إلى أهليهم أبدا وزين ذلك﴾ [الفَتح: 12]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Rárá (kì í ṣe iṣẹ́ kan l’ó di yín lọ́wọ́ láti lọ jagun, àmọ́) ẹ ti lérò pé Òjíṣẹ́ àti àwọn onígbàgbọ́ òdodo kò níí padà sí ọ̀dọ̀ ará ilé wọn mọ́ láéláé. Wọ́n ṣe ìyẹn ni ọ̀ṣọ́ sínú ọkàn yín. Ẹ sì ro èrò aburú. Ẹ sì jẹ́ ìjọ ìparun
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek