×

Ti o ba je pe awon t’o sai gbagbo gbogun dide si 48:22 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Fath ⮕ (48:22) ayat 22 in Yoruba

48:22 Surah Al-Fath ayat 22 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fath ayat 22 - الفَتح - Page - Juz 26

﴿وَلَوۡ قَٰتَلَكُمُ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ لَوَلَّوُاْ ٱلۡأَدۡبَٰرَ ثُمَّ لَا يَجِدُونَ وَلِيّٗا وَلَا نَصِيرٗا ﴾
[الفَتح: 22]

Ti o ba je pe awon t’o sai gbagbo gbogun dide si yin ni, won iba peyin da (lati sagun fun yin). Leyin naa, won ko nii ri alaabo tabi alaranse kan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولو قاتلكم الذين كفروا لولوا الأدبار ثم لا يجدون وليا ولا نصيرا, باللغة اليوربا

﴿ولو قاتلكم الذين كفروا لولوا الأدبار ثم لا يجدون وليا ولا نصيرا﴾ [الفَتح: 22]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Tí ó bá jẹ́ pé àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ gbógun dìde si yín ni, wọn ìbá pẹ̀yìn dà (láti ságun fun yín). Lẹ́yìn náà, wọn kò níí rí aláàbò tàbí alárànṣe kan
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek