Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fath ayat 8 - الفَتح - Page - Juz 26
﴿إِنَّآ أَرۡسَلۡنَٰكَ شَٰهِدٗا وَمُبَشِّرٗا وَنَذِيرٗا ﴾
[الفَتح: 8]
﴿إنا أرسلناك شاهدا ومبشرا ونذيرا﴾ [الفَتح: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa rán ọ níṣẹ́ (pé kí o jẹ́) olùjẹ́rìí, oníròó-ìdùnnú àti olùkìlọ̀ |