×

Awon onigbagbo ododo ni awon t’o gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re, 49:15 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-hujurat ⮕ (49:15) ayat 15 in Yoruba

49:15 Surah Al-hujurat ayat 15 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-hujurat ayat 15 - الحُجُرَات - Page - Juz 26

﴿إِنَّمَا ٱلۡمُؤۡمِنُونَ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ بِٱللَّهِ وَرَسُولِهِۦ ثُمَّ لَمۡ يَرۡتَابُواْ وَجَٰهَدُواْ بِأَمۡوَٰلِهِمۡ وَأَنفُسِهِمۡ فِي سَبِيلِ ٱللَّهِۚ أُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلصَّٰدِقُونَ ﴾
[الحُجُرَات: 15]

Awon onigbagbo ododo ni awon t’o gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re, leyin naa ti won ko seyemeji, ti won si fi dukia won ati emi won jagun fun esin Allahu. Awon wonyen, awon ni olododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إنما المؤمنون الذين آمنوا بالله ورسوله ثم لم يرتابوا وجاهدوا بأموالهم وأنفسهم, باللغة اليوربا

﴿إنما المؤمنون الذين آمنوا بالله ورسوله ثم لم يرتابوا وجاهدوا بأموالهم وأنفسهم﴾ [الحُجُرَات: 15]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn onígbàgbọ́ òdodo ni àwọn t’ó gbàgbọ́ nínú Allāhu àti Òjíṣẹ́ Rẹ̀, lẹ́yìn náà tí wọn kò ṣeyèméjì, tí wọ́n sì fi dúkìá wọn àti ẹ̀mí wọn jagun fún ẹ̀sìn Allāhu. Àwọn wọ̀nyẹn, àwọn ni olódodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek