Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 12 - قٓ - Page - Juz 26
﴿كَذَّبَتۡ قَبۡلَهُمۡ قَوۡمُ نُوحٖ وَأَصۡحَٰبُ ٱلرَّسِّ وَثَمُودُ ﴾
[قٓ: 12]
﴿كذبت قبلهم قوم نوح وأصحاب الرس وثمود﴾ [قٓ: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ènìyàn (Ànábì) Nūh, àwọn ènìyàn Rass àti àwọn (ènìyàn) Thamūd pe òdodo nírọ́ ṣíwájú wọn |