Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 14 - قٓ - Page - Juz 26
﴿وَأَصۡحَٰبُ ٱلۡأَيۡكَةِ وَقَوۡمُ تُبَّعٖۚ كُلّٞ كَذَّبَ ٱلرُّسُلَ فَحَقَّ وَعِيدِ ﴾
[قٓ: 14]
﴿وأصحاب الأيكة وقوم تبع كل كذب الرسل فحق وعيد﴾ [قٓ: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni àti àwọn ará ’Aekah àti àwọn ìjọ Tubba‘u; gbogbo wọn pe àwọn Òjíṣẹ́ ní òpùrọ́. Nítorí náà, ìlérí Mi sì di ẹ̀tọ́ (lórí wọn) |