Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 15 - قٓ - Page - Juz 26
﴿أَفَعَيِينَا بِٱلۡخَلۡقِ ٱلۡأَوَّلِۚ بَلۡ هُمۡ فِي لَبۡسٖ مِّنۡ خَلۡقٖ جَدِيدٖ ﴾
[قٓ: 15]
﴿أفعيينا بالخلق الأول بل هم في لبس من خلق جديد﴾ [قٓ: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ǹjẹ́ ìṣẹ̀dá àkọ́kọ́ kó agara bá Wa bí? Rárá, wọ́n wà nínú iyèméjì nípa ìṣẹ̀dá (wọn) ní titun ni |