Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 3 - قٓ - Page - Juz 26
﴿أَءِذَا مِتۡنَا وَكُنَّا تُرَابٗاۖ ذَٰلِكَ رَجۡعُۢ بَعِيدٞ ﴾
[قٓ: 3]
﴿أئذا متنا وكنا ترابا ذلك رجع بعيد﴾ [قٓ: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé nígbà tí a bá ti kú, tí a ti di erùpẹ̀ (ni a óò tún jí dìde padà). Ìyẹn ni ìdápadà tó jìnnà (sí n̄ǹkan tí ó lè ṣẹlẹ̀) |