Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 35 - قٓ - Page - Juz 26
﴿لَهُم مَّا يَشَآءُونَ فِيهَا وَلَدَيۡنَا مَزِيدٞ ﴾
[قٓ: 35]
﴿لهم ما يشاءون فيها ولدينا مزيد﴾ [قٓ: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ohun tí wọ́n ń fẹ́ wà nínú rẹ̀. Àlékún sì tún wà ní ọ̀dọ̀ Wa |