Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 41 - قٓ - Page - Juz 26
﴿وَٱسۡتَمِعۡ يَوۡمَ يُنَادِ ٱلۡمُنَادِ مِن مَّكَانٖ قَرِيبٖ ﴾
[قٓ: 41]
﴿واستمع يوم يناد المناد من مكان قريب﴾ [قٓ: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí o sì tẹ́tí sí ọjọ́ tí olùpèpè yóò pèpè láti àyè kan t’ó súnmọ́ |