Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 42 - قٓ - Page - Juz 26
﴿يَوۡمَ يَسۡمَعُونَ ٱلصَّيۡحَةَ بِٱلۡحَقِّۚ ذَٰلِكَ يَوۡمُ ٱلۡخُرُوجِ ﴾
[قٓ: 42]
﴿يوم يسمعون الصيحة بالحق ذلك يوم الخروج﴾ [قٓ: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọjọ́ tí wọn yóò gbọ́ igbe pẹ̀lú òdodo. Ìyẹn ni ọjọ́ ìjáde ẹ̀dá (láti inú sàréè) |