Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 5 - قٓ - Page - Juz 26
﴿بَلۡ كَذَّبُواْ بِٱلۡحَقِّ لَمَّا جَآءَهُمۡ فَهُمۡ فِيٓ أَمۡرٖ مَّرِيجٍ ﴾
[قٓ: 5]
﴿بل كذبوا بالحق لما جاءهم فهم في أمر مريج﴾ [قٓ: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Síbẹ̀síbẹ̀ wọ́n pe òdodo (al-Ƙur’ān) ní irọ́ nígbà tí ó dé bá wọn. Nítorí náà, wọ́n ti wà nínú ìdààmú |