Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 19 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿وَفِيٓ أَمۡوَٰلِهِمۡ حَقّٞ لِّلسَّآئِلِ وَٱلۡمَحۡرُومِ ﴾
[الذَّاريَات: 19]
﴿وفي أموالهم حق للسائل والمحروم﴾ [الذَّاريَات: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nínú dúkìá wọn, wọ́n ní ojúṣe tí wọ́n ń ṣe fún alágbe àti ẹni tí A ṣe arísìkí ní èèwọ̀ fún |