Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 28 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿فَأَوۡجَسَ مِنۡهُمۡ خِيفَةٗۖ قَالُواْ لَا تَخَفۡۖ وَبَشَّرُوهُ بِغُلَٰمٍ عَلِيمٖ ﴾
[الذَّاريَات: 28]
﴿فأوجس منهم خيفة قالوا لا تخف وبشروه بغلام عليم﴾ [الذَّاريَات: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà náà, ó ní ìpáyà wọn nínú ọkàn. Wọ́n sọ pé: "Má ṣe páyà." Wọ́n sì fún un ní ìró ìdùnnú nípa bíbí ọmọkùnrin onímọ̀ kan |