Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 41 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَفِي عَادٍ إِذۡ أَرۡسَلۡنَا عَلَيۡهِمُ ٱلرِّيحَ ٱلۡعَقِيمَ ﴾
[الذَّاريَات: 41]
﴿وفي عاد إذ أرسلنا عليهم الريح العقيم﴾ [الذَّاريَات: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àmì tún wà) lára ìjọ ‘Ād. (Rántí) nígbà tí A rán atẹ́gùn ìparun sí wọn |