Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 40 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿فَأَخَذۡنَٰهُ وَجُنُودَهُۥ فَنَبَذۡنَٰهُمۡ فِي ٱلۡيَمِّ وَهُوَ مُلِيمٞ ﴾
[الذَّاريَات: 40]
﴿فأخذناه وجنوده فنبذناهم في اليم وهو مليم﴾ [الذَّاريَات: 40]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A mú òun àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀. A sì jù wọ́n sínú agbami odò nígbà tí ó jẹ́ alábùkù |