Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 50 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿فَفِرُّوٓاْ إِلَى ٱللَّهِۖ إِنِّي لَكُم مِّنۡهُ نَذِيرٞ مُّبِينٞ ﴾
[الذَّاريَات: 50]
﴿ففروا إلى الله إني لكم منه نذير مبين﴾ [الذَّاريَات: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹ sá lọ sí ọ̀dọ̀ Allāhu (nípa ìronúpìwàdà). Dájúdájú èmi ni olùkìlọ̀ pọ́nńbélé fun yín láti ọ̀dọ̀ Rẹ̀ |