Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 49 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَمِن كُلِّ شَيۡءٍ خَلَقۡنَا زَوۡجَيۡنِ لَعَلَّكُمۡ تَذَكَّرُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 49]
﴿ومن كل شيء خلقنا زوجين لعلكم تذكرون﴾ [الذَّاريَات: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé gbogbo n̄ǹkan ni A ṣẹ̀dá ní oríṣi méjì-méjì nítorí kí ẹ lè lo ìrántí |