Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 51 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَلَا تَجۡعَلُواْ مَعَ ٱللَّهِ إِلَٰهًا ءَاخَرَۖ إِنِّي لَكُم مِّنۡهُ نَذِيرٞ مُّبِينٞ ﴾
[الذَّاريَات: 51]
﴿ولا تجعلوا مع الله إلها آخر إني لكم منه نذير مبين﴾ [الذَّاريَات: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ má ṣe mú ọlọ́hun mìíràn mọ́ Allāhu. Dájúdájú èmi ni olùkìlọ̀ pọ́nńbélé fun yín láti ọ̀dọ̀ Rẹ̀ |